Baba ati iya mose je eru ni Egipti. Farao oba Egipti fi iya jẹ awọn eru ko si fe ki wọn ni ọmọ pupọ. Iya mose gbe pamọ fun osu mẹta lẹyin igba to bi titi ti o fi tobi. O si wun apẹẹrẹ ofi oda mo ara apẹẹrẹ naa, o si gbe Mose sinu apẹẹrẹ. Ni owurọ ojojumọ ki awọn aladugbo rẹ to ji yo gbe Mose lọ seti odo. Miriamu egbon rẹ yo sa pamọ sinu igbo lati ma wo o.
The Biblical story of Moses is beautifully told in Yoruba language, with beautiful pictures for children, teens, young adults and the young at heart.